Jeremáyà 48:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó pa Móábù run, a ó sì gba àwọn ìlú rẹ̀;a ó sì dúńbú àwọn arẹwà ọkùnrin rẹ̀,”ni Ọba wí, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Olúwa àwọn ọmọ-ogun.

Jeremáyà 48

Jeremáyà 48:7-24