Jeremáyà 48:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìfibú ni fún ẹni tí ó dúró láti ṣe iṣẹ́ Olúwa,ìfibú ni fún ẹni tí ó pa idà mọ́ fún ìtàjẹ̀sílẹ̀.

Jeremáyà 48

Jeremáyà 48:7-13