Jeremáyà 47:6-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. “Ẹ̀yin kígbe, ‘Yé è, idà Olúwa,yóò ti pẹ́ tó tí ìwọ yóò sinmi?Padà sínú àkọ̀ re;sinmi kí o sì dákẹ́ jẹ́ẹ́.’

7. Ṣùgbọ́n báwo ni yóò ṣe sinmi,nígbà tí Olúwa ti pàṣẹ fún un,nígbà tí ó ti pa á láṣẹláti dojúkọ Áṣíkélónì àti agbégbé rẹ̀.”

Jeremáyà 47