Jeremáyà 46:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Éjíbítì dìde bí odò náà,bí omi odò tí ń ru.Ó sì wí pé, ‘Èmi yóò dìde, n ó sì bo gbogbo ilẹ̀ ayé.’Èmi yóò pa orílẹ̀ èdè àti àwọn ènìyàn rẹ̀ run.

Jeremáyà 46

Jeremáyà 46:2-13