Jeremáyà 46:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Éjíbítì yóò pòṣé bí ejò tí ń sábí ọmọ ogun ṣe ń tọ̀ ọ́ wá pẹ̀lú agbára.Wọn ó tọ̀ ọ́ wá pẹ̀lú àáké,gẹ́gẹ́ bí i ti agégi.

Jeremáyà 46

Jeremáyà 46:18-28