Jeremáyà 46:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí èmi ti wà láàyè,” ni Ọba,ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Olúwa àwọn ọmọ ogun wí pé,“nítòótọ́ gẹ́gẹ́ bí Tábórì láàrin àwọn òkè àtigẹ́gẹ́ bi Kámẹ́lì lẹ́bàá òkun bẹ́ẹ̀ ni òun yóò dé.

Jeremáyà 46

Jeremáyà 46:13-26