Jeremáyà 46:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kéde èyí ní Éjíbítì, sì sọ ọ́ ní Nígídò,sọ ọ́ ní Mémífísì àti Táfánésì:‘Dúró sí àyè rẹ kí o sì múra sílẹ̀,nítorí pé idà náà ń pa àwọn tí ó yí ọ ká.’

Jeremáyà 46

Jeremáyà 46:12-22