Jeremáyà 46:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gòkè lọ sí Gílíádì, kí o sì mú ìkunra,ìwọ wúndíá Éjíbítì.Ṣùgbọ́n ní asán ni ìwọ ń lo oògùn,kì yóò sí ìwòsàn fún ọ.

Jeremáyà 46

Jeremáyà 46:5-20