Jeremáyà 43:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní Tẹ́ḿpìlì ni yóò ti fọ́ ère ilé òòrùn tí ó wà ní ilẹ̀ Ìjíbítì túútúú, yóò sì sun àwọn Tẹ́ḿpìlì àwọn òrìṣà Éjíbítì.’ ”

Jeremáyà 43

Jeremáyà 43:6-13