Jeremáyà 42:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni a ó pa Jóhánánì ọmọkùnrin Káréà àti gbogbo àwọn ọmọ-ogun tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀; àti gbogbo àwọn ènìyàn láti orí ẹní tí ó kéré dé orí ẹni ńlá.

Jeremáyà 42

Jeremáyà 42:2-9