Jeremáyà 42:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì ṣe, idà tí ẹ̀yin bẹ̀rù yóò sì lé e yín bá níbẹ̀; àti ìyànu náà tí ẹ̀yin ń bẹ̀rù yóò sì tẹ̀lé yín lọ sí Éjíbítì àti pé ibẹ̀ ni ẹ̀yin yóò kú sí.

Jeremáyà 42

Jeremáyà 42:6-22