Jeremáyà 42:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ní gbogbo àwọn ọmọ ogun àti Jóhánánì ọmọkùnrin Káréà àti Jésánáyà omọkùnrin Hòsáyà àti kékeré títí dé orí ẹni ńlá wá.

Jeremáyà 42

Jeremáyà 42:1-5