Jeremáyà 41:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísímáẹ́lì ọmọkùnrin Nétanáyà jáde kúrò láti Mísípà láti lọ pàdé wọn. Ó sì ń sunkún bí ó ti ṣe ń lọ, nígbà tí ó pàdé wọn, ó wí pé, “Ẹwá sọ́dọ̀ Jedaláyà ọmọkùnrin Álíkámù.”

Jeremáyà 41

Jeremáyà 41:3-8