Jeremáyà 40:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Jedáláyà ọmọ Áhíkámù sọ fún Jóhánánì ọmọ Káréà pé, “Má ṣe ṣe nǹkan yìí! Nítorí nǹkan tí ò ń sọ nípa Íṣímáẹ́lì kì í ṣe òtítọ́.”

Jeremáyà 40

Jeremáyà 40:7-16