Jeremáyà 4:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ariwo àwọn ẹlẹ́ṣin àti àwọn tafàtafàgbogbo ìlú yóò sálọ.Ọ̀pọ̀ sálọ sínú igbó;ọ̀pọ̀ yóò sì gun orí àpáta lọ.Gbogbo ìlú náà sì di ahoro;kò sì sí ẹnìkan nínú rẹ̀.

Jeremáyà 4

Jeremáyà 4:25-31