Jeremáyà 4:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo bojú wò, ilẹ̀ eléṣo, ó sì di aṣálẹ̀gbogbo àwọn ìlú inú rẹ̀ sì ṣubú sínú ìparunníwájú Olúwa àti níwájú ríru ìbínú rẹ̀.

Jeremáyà 4

Jeremáyà 4:20-28