Jeremáyà 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sọ èyí fún àwọn orílẹ̀ èdè,kéde rẹ̀ fún Jérúsálẹ́mù pé:‘Ọmọ ogun ọ̀tá ń bọ̀ láti ilẹ̀ jínjìn wáWọ́n sì ń kígbe ogun láti dojú kọ ìlú Júdà.

Jeremáyà 4

Jeremáyà 4:7-25