Jeremáyà 39:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ránṣẹ́ láti mú Jeremáyà kúrò nínú túbú. Wọ́n gbé e lọ fún Jedalíyà ọmọ Álúkámù ọmọ Sápámù láti mú padà lọ sí ilé àti máa wà pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ̀.

Jeremáyà 39

Jeremáyà 39:11-18