Jeremáyà 39:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìnyìí, Nebukadinésárì Ọba àwọn Bábílónì pàṣẹ lórí Jeremáyà, láti ọ̀dọ̀ Nebusárádánì olórí ogun wá wí pé:

Jeremáyà 39

Jeremáyà 39:6-12