Jeremáyà 38:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé èyí ni ohun tí Olúwa wí: ‘Ìdánilójú wà wí pé a ó fi ìlú náà lé ọwọ́ àwọn ọmọ ogun Bábílónì; tí yóò sì kó wa nígbékùn.’ ”

Jeremáyà 38

Jeremáyà 38:1-11