Jeremáyà 38:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Sedekáyà sọ fún Jeremáyà pé, “Mò ń bẹ̀rù àwọn Júù tó ti sálọ sí ilẹ̀ Bábílónì, nítorí pé àwọn ará Bábílónì lè fà mí lé wọn lọ́wọ́ láti fìyà jẹ mí.”

Jeremáyà 38

Jeremáyà 38:10-26