Jeremáyà 37:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣedekáyà Ọba sì rán Jéhúkálì ọmọ Semeláyà àti Sefanáyà ọmọ Máséyà sí Jeremáyà wòlíì wí pé, “Jọ̀wọ́ gbàdúrà sí Olúwa Ọlọ́run wa fún wa.”

Jeremáyà 37

Jeremáyà 37:1-12