Jeremáyà 37:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbo ni àwọn wòlíì yín tí wọ́n ń sọ àṣọtẹ́lẹ̀ fún-un yín wí pé Ọba Bábílónì kò ní gbógun tì yín wá?

Jeremáyà 37

Jeremáyà 37:10-21