Jeremáyà 37:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jeremáyà múra láti fi ìlú náà sílẹ̀, láti lọ sí olú ìlú Bẹ́ńjámínì láti gba ẹ̀tọ́ rẹ̀ nínú ohun ìní láàrin àwọn ènìyàn tó wà níbẹ̀.

Jeremáyà 37

Jeremáyà 37:5-21