Jeremáyà 37:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sedekáyà ọmọ Jòsáyà sì jọba nípò Kóráyà ọmọ Jéhóíákímù ẹni tí Nebukadinésárì Ọba Bábílónì fi jẹ Ọba ní ilẹ̀ Júdà.

Jeremáyà 37

Jeremáyà 37:1-5