Jeremáyà 36:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wí pé, tún mú ìwé kíká mìíràn kí o sì kọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí ó wà nínú ìwé kíká èkínní tí Jéhóíákímù Ọba Júdà fi jóná.

Jeremáyà 36

Jeremáyà 36:23-32