Jeremáyà 36:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dípò èyí Ọba pàṣẹ fún Jeremélì ọmọ Hamelékì, Seráyà ọmọ Ásíráélì àti Selemáyà ọmọ Ábídélì láti mú Bárúkì akọ̀wé àti Jeremáyà wòlíì ṣùgbọ́n Ọlọ́run fi wọ́n pamọ́.

Jeremáyà 36

Jeremáyà 36:20-31