Jeremáyà 36:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì jẹ́ ìgbà òtútù nínú oṣù kẹsàn-án, Ọba sì jókòó ní ẹ̀bá iná àrò, iná náà sì ń jó ní iwájú rẹ̀.

Jeremáyà 36

Jeremáyà 36:16-31