Jeremáyà 36:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bárúkì sì dá wọn lóhùn wí pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, láti ẹnu rẹ̀ ni, ó sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ báyìí fún mi, èmi sì fi tàdáwà kọ wọ́n sínú ìwé náà.”

Jeremáyà 36

Jeremáyà 36:17-25