Jeremáyà 35:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ sí ilé àwọn ọmọ Rékábù, kí o sì bá wọn sọ̀rọ̀, kí o sì mú wọn wá sí ilé Olúwa, sí ọ̀kan nínú iyàrá wọ̀n-ọn-nì, kí o sì fún wọn ní ọtí wáìnì mu.”

Jeremáyà 35

Jeremáyà 35:1-12