Jeremáyà 34:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí oníkálùkù lè jẹ́ kí ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrin tí í ṣe Hébérù lọ lọ́fẹ̀ẹ́, kí ẹnikẹ́ni kí ó má mú ará Júdà arákùnrin rẹ̀ sìn.

Jeremáyà 34

Jeremáyà 34:2-10