Jeremáyà 33:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó wẹ̀ wọ́n nù kúrò nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ti ṣẹ sími. Èmi ó sì dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ àìṣedédé wọn sí mi jìn wọ́n.

Jeremáyà 33

Jeremáyà 33:1-18