Jeremáyà 33:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ìjà pẹ̀lú Kálídéà: ‘Wọn yóò kún fún ọ̀pọ̀ òkú ọmọkùnrin tí èmi yóò pa nínú ìbínú àti nínú ìrunú mi. Èmi ó pa ojú mi mọ́ kúrò ní ìlú yìí nítorí gbogbo búburú wọn.

Jeremáyà 33

Jeremáyà 33:1-15