Jeremáyà 33:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Pè mí, èmi ó sì dá ọ lóhùn, èmi ó sì sọ ohun alágbára ńlá àti ọ̀pọ̀ ohun tí kò ṣe é wádìí tí ìwọ kò mọ̀ fún ọ.’

Jeremáyà 33

Jeremáyà 33:1-8