Jeremáyà 33:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó mú àwọn ọmọlẹ́yìn Dáfídì ìránṣẹ́ mi àti Léfì tí ó jẹ́ oníwàásù níwájú mi di bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run, tí kò ṣe é kà àti bí iyẹ̀pẹ̀ ojú òkun tí kò ṣe é wọ̀n.’ ”

Jeremáyà 33

Jeremáyà 33:19-26