Jeremáyà 32:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hánámélì ọmọkùnrin Sálúmù ẹ̀gbọ́n rẹ̀ yóò tọ̀ ọ́ wá pé, ‘Ra pápá mi tí ó wà ní Ánátótì; nítorí gẹ́gẹ́ bí ẹni tó sún mọ́ wọn, ẹ̀tọ́ àti ìṣe rẹ ní láti rà á.’

Jeremáyà 32

Jeremáyà 32:6-16