Jeremáyà 32:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí bayìí ni Olúwa wí: Gẹ́gẹ́ bí èmi ti mú gbogbo ibi ńlá yìí wá sórí àwọn ènìyàn yìí, bẹ́ẹ̀ ni èmi ó mú gbogbo rere tí èmi ti sọ nípa ti wọn wá sórí wọn.

Jeremáyà 32

Jeremáyà 32:40-43