Jeremáyà 32:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó kó wọn jọ láti gbogbo ilẹ̀ tí mo ti lé wọn kúrò ní ìgbà ìbínú àti ìkáàánú ńlá mi. Èmi yóò mú wọn padà wá sí ilẹ̀ yìí; èmi ó sì jẹ́ kí wọn ó máa gbé láìléwu.

Jeremáyà 32

Jeremáyà 32:34-41