Jeremáyà 32:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n kó òrìṣà ìríra wọn jọ sí inú ilé tí wọ́n fi orúkọ mi pè, wọ́n sì sọ́ di àìmọ́.

Jeremáyà 32

Jeremáyà 32:26-44