Jeremáyà 32:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ fún wọn nílẹ̀ yìí, èyí tí o ti ṣèlérí fún àwọn baba ńlá wọn; ilẹ̀ tí ń ṣàn fún wàrà àti oyin.

Jeremáyà 32

Jeremáyà 32:16-31