Jeremáyà 32:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Títóbi ni iṣẹ́ rẹ, agbára sì ni ìṣe rẹ. Ojú rẹ sí sí gbogbo ọ̀nà àwọn ọkùnrin, ó sì fún olúkúlùkù gẹ́gẹ́ bí ìṣe àti ìwà rẹ̀.

Jeremáyà 32

Jeremáyà 32:9-27