Jeremáyà 31:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, Èmi yóò mú wọn wá láti ilẹ̀ àríwá;èmi yóò kó gbogbo wọn jọ láti òpin ayé.Lára wọn ni yóò jẹ́ afọ́jú àti arọ,aboyún àti obìnrin tí ń rọbí,ọ̀pọ̀ ènìyàn yóò wá.

Jeremáyà 31

Jeremáyà 31:1-15