Jeremáyà 31:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítòótọ́, èmi ti gbọ́ ìpohùnréré Éfúráímù wí pé,‘Ìwọ ti bá mi wí gẹ́gẹ́ bí ọmọ màlúù tí a kò kọ́èmi sì ti gbọ́ ìbáwí.Ràmípadà, Èmi yóò sì yípadà,nítorí ìwọ ni Olúwa Ọlọ́run mi.

Jeremáyà 31

Jeremáyà 31:10-27