Jeremáyà 30:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, ìbínú Ọlọ́run yóò tú jáde,ìjì líle yóò sì sọ̀kalẹ̀ sórí àwọn ènìyàn búburú.

Jeremáyà 30

Jeremáyà 30:15-24