Jeremáyà 30:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí, pé: ‘Ìwọ kọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo ti bá ọ sọ sínú ìwé kan.

Jeremáyà 30

Jeremáyà 30:1-6