Jeremáyà 30:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ẹnu wọn ni orin ọpẹ́ àtiìyìn yóò sì ti máa jáde.Èmi yóò sọ wọ́n di púpọ̀,wọn kì yóò sì dínkù ní iye,Èmi yóò fi ọlá fún wọn,wọn kò sì ní di ẹni àbùkù.

Jeremáyà 30

Jeremáyà 30:17-23