Jeremáyà 30:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí ni ohun tí Olúwa wí:“ ‘Ọgbẹ́ yín kò gbóògùn,bẹ́ẹ̀ ni egbò yín kọjá ìwòsàn.

Jeremáyà 30

Jeremáyà 30:9-19