Jeremáyà 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo fún Ísírẹ́lì aláìnígbàgbọ́ ní ìwé ìkọ̀sílẹ̀, mo sì ké wọn kúrò nítorí gbogbo àgbèrè wọn. Ṣíbẹ̀ mo rí pé Júdà tí ó jẹ́ arábìnrin rẹ̀ kò bẹ̀rù, òun náà sì jáde lọ láti lọ ṣe àgbèrè.

Jeremáyà 3

Jeremáyà 3:7-12