Jeremáyà 3:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìgbà èwe wa ni àwọn òrìṣà ìtìjú tipa èso iṣẹ́ àwọn baba wa,ọ̀wọ́ ẹran wọn àti agbo ẹran wọn,ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin wọn.

Jeremáyà 3

Jeremáyà 3:16-25