Jeremáyà 3:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Padà, ẹ̀yin ènìyàn aláìnígbàgbọ́,Èmi ó wo ìpadàsẹ́yìn kúrò ní ọ̀nà títọ́ rẹ sàn.”“Bẹ́ẹ̀, ni a ó wá sọ́dọ̀ rẹnítorí ìwọ ni Olúwa Ọlọ́run wa.

Jeremáyà 3

Jeremáyà 3:16-25